[Verse 1]
Awon adan fo loke
Wan foka si oju Orun
Wan o ma mo ibi won lo
Eledua lo n shey ike won
Ko keyin si é Oré o
O wun o n wa
O wa ni waju re
[Hook]
Adedotun…….
Oyindamola mi…….
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o………….
[Verse 2]
Awon adan fo loke
Ni igba igba
Won ku oju orun
Won o ma mo iwun wan n je
Eledua lo n sho wan
Lo n bo wan
Ko pamo si é
Oré ooooooo
O wa lo sokoto
O wa lapo Sokoto
[Hook]
Adedotun…….
Oyindamola mi…….
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o………….
(X2)
Ko pamo si é
Oré o
Owun o n wa
O wa ni waju re
Ore o……..